Home LÁGBO ÀRÍYÁ Idi ti emi ati Waje fi je ore timotimo – Omowumi
LÁGBO ÀRÍYÁ - Orisirisi - May 11, 2019

Idi ti emi ati Waje fi je ore timotimo – Omowumi

Olamide Yusuf

Waje (left) and Omowumi

Ti a ba n soro nipa awon olorin Nigeria ti won sun mo ara won timotimo, Waje ati Omowumi je okan Pataki lara won ni.
Awon mejeeji ti je ore fun igba pipe, ti won si sese gbe orin kan jade.

Omowumi ti wa so asiri to wa nidii ore won.
O ni bo tile je pe awon o le ma ja leekookan, awon maa wa ona lati paari e ni.

Omowumi ni o rorun lati ba obirin sise paapa awon to mo ise daada.
O ni opo igba lo je pe awon eniyan maa n ro pe awon obirin ko ja fafa, sugbon ko ri bee.
O ni ti a ba fun obirin ni ise lati se, ero re ni bi yoo ti se ise naa daada ki iru eni be le pada wa ba won sise.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…