Home iroyin Agba onifiimu, Eddie Ugboma, di oloogbe
iroyin - LÁGBO ÀRÍYÁ - Orisirisi - May 11, 2019

Agba onifiimu, Eddie Ugboma, di oloogbe

Ugbomah

Gbajugbaja onise fiimu, Eddie Ugbomah, ti di oloogbe bayii.
O ku leyin aisan kan to ti da a gunle fun igba die.
Owo to je aadota milionu ni o nilo fun ise abe to ye ki won se fun un ni ilu oyinbo.
Eddie Ugbomah gbe orisirisi fiimu sita bi, Idide ati Isubu Oyenusi( Rise and fall of Oyenusi) ni odun 1979; Apalara, ere to da lori iku Alfa Apalara ni Oko Awo ti Ilu Eko.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…