Home ÀKỌ̀TUN PDP máa jáwé olúborí ní Kóòtù Supreme – Davido
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - May 9, 2019

PDP máa jáwé olúborí ní Kóòtù Supreme – Davido

Gbajugbaja akorin, David Adeleke ti gbogbo eniyan mo si Davido ni o ti n leri leka lori idajo ile-ejo kotemi-lorun to waye lonii. Ejo naa segbe fun egbe oselu APC, ile-ejo ni Gboyega Oyetola lo jawe olubori gege bii gomina ni ipinle Osun, bi o tile je pe Ademola Adeleke lo jawe olubori ni ile-ejo tiribuna ni osu to koja.
Egbe oselu PDP ni ejo naa ko te awon lorun nipa idi eyi, awon ni lati lo si ile-ejo to ga ju to n je Supreme. Eyi ni Davido ni o da oun loju to ada pe Seneto Ademola Adeleke lo maa jawe olubori nibi ejo naa laipe.
Egbe oselu APC ti gbe ilu ti won si bere si ni jo kiri ilu pelu gomina ipinle naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…