Tottenham sẹ́ eegun ẹ̀yìn Ajax
Ale oni ni iko egbe agbaboolu Tottenham woya ija pelu akegbe won Ajax. Bi oju ogun naa se le to lati le wo iko to maa woya ija pelu iko agbaboolu Liverpool, egbe agbaboolu Tottenham si jawe olubori pelu ami ayo meta si meji.
Eyi tumo si wi pe Tottenham lo maa waa ko pelu egbe agbaboolu ti Liverpool.
Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.
Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…