Home ÀKỌ̀TUN Ọ̀jọ̀gbọ́n OAU fi mílíọ̀nù márùn-ún gba ìdáǹdè
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - May 7, 2019

Ọ̀jọ̀gbọ́n OAU fi mílíọ̀nù márùn-ún gba ìdáǹdè

Ojogbon Fasiti Obafemi Awolowo to wa ni Ile-Ife ni ori ti ko yo lowo awon ajinigbe bayii. Ojo Isinmi to koja ni won ji Ojogbon Olayinka Adegbehingbe gbe ki baba naa to san owo ni ana ode yi.
Milionu marun-un le die owo naira ni ebi ati ara fi gbara ki ojogbon yii to bo lowo awon eniyan yii. O ni lati ori milionu ogbon ni idunadura ti bere ki adura to gba lori iye ti oun ko sile. Alukoro ile-iwe naa, Abiodun Olarewaju fi idi idande yii mule.
Ojogbon yii ni oun dupe lowo ebi ati ara pelu awon aladura lori oun. O tun pese ise fun awon ara ilu. O ni ainise wa lara iwa odaran to gbile ni ilu.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…