Mayọkun sọ̀kò ọ̀rọ̀ sí Burna Boy
Akorin hip hop, Mayorkun, ti soko oro si akegbe re kan ti a mo si Burna Boy.
O se eyi latari ohun ti Burna Boy so pe ki won maa gbo tabi wo orin eniyan ni lemolemo ko tumo sip e onitohun ni ebun orin.
Eyi dun Mayokun nitori o sese se ikede pe won ti wo orin oun lori ero alatagba niwon aadorin milionu – 70m times.
Laipe re ni Burna Boy wa bu enu ate lu ohun ti awon oloyinbo n pe ni live streaming naa.
Burna boy condemn musicians who measure their talent based on streaming numbers
Nigba ti Mayorkun n fesi le eyi, o ni bi won se sugbaa orin Burna Boy ti akole re n je ‘Ye’ naa niyen ti o fi di ilumoika.
O ni bawo lo se wa maa dori akayin toun ti akara a di egungun.
Loju ti Mayorkun, alanikanjopon fee ni Burna Boy.
Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja
Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…