Home ÀKỌ̀TUN Ajínigbé jí Ọ̀jọ̀gbọ́n Fásítì Ifẹ̀ gbé
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - May 7, 2019

Ajínigbé jí Ọ̀jọ̀gbọ́n Fásítì Ifẹ̀ gbé

Opopona Ile-Ife si Ibadan ni awon ajinigbe ti da Ojogbon Yinka Adegbehingbe lona ti won si da wahala sile ni oju ona naa.
Ni igba ti awon eniyan koko gburo awon eniyan yii, inu igbo kun bamu bii igba ti awon eniyan n sise ode ni. Onikaluku bere si ni sa asala fun emi won.
Awon kan tile koko ro pe awon adigunjale ni, igba ti won ji Ojogbon naa gbe ni awon eniyan to mo pe awon ajinigbe ni. Ogangan ilu Asejire si Ikire ni isele buruku naa ti sele. Titi di asiko ti a n ko iroyin yii jo ni awon ajinigbe naa ko tii so iye tabi ohun ti won fe gba.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…