Home ÀKỌ̀TUN Ẹ gbà wá o! Wọ́n fẹ́ fún Adeleke ní májèlé jẹ ni o – PDP
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - May 6, 2019

Ẹ gbà wá o! Wọ́n fẹ́ fún Adeleke ní májèlé jẹ ni o – PDP

Egbe oselu PDP ni won ke gbajare faraye pe ejo lonii, ejo lola nipa iwe eri Seneto Ademola Adeleke. Ejo yii ti n pooyi kootu lati bii osu melo kan seyin.
Egbe oselu APC ni o fesun kan seneto Adeleke pe ko ni iwe eri olodun kewaa ti o si lodi si ofin ile wa fun iru eni bee lati di gomina ni ipinle Kankan ni orileede yii.
Ejo yii ni o n gbe Adeleke poori kootu. Eyi wa mu ki egbe PDP pariwo sita pe awon funra si egbe oselu APC pe won fe fun Adeleke ni majele je ni ahamo ojoojumo naa. Won ni ki omo Naijiria jowo ma se je ki imo ota se lori Adeleke.
Ile-ejo ni Seneto Adeleke letoo labe ofin lati lo si ilu Oba nitori ipo re ni orileede yii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…