Home ÀKỌ̀TUN Abuja Straight ! – Tajudeen Agbede
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - May 4, 2019

Abuja Straight ! – Tajudeen Agbede

Ariwo yii ni awon omo onimoto ati awon ololufe Alhaji Tajudeen Agbede fi bonu ni papa isere ilu Agege ni ayajo awon osise.
Agbede ni alaga awon egbe NURTW ti ipinle Eko. IROYIN OWURO wa feti koo lenu awon omo egbe pe Agbede ni gbogbo awon fowo si ko lo je olori ni ilu Abuja. Alaga ko kuku ba enikankan soro, o kan n yan bi ologun ni papa isere naa ni.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…