Home iroyin Tonto Dikeh di eni gbogbo aye n wenu si lara leyin to ni baba omo oun ko le ba obinrin sun karakara
iroyin - Orisirisi - May 3, 2019

Tonto Dikeh di eni gbogbo aye n wenu si lara leyin to ni baba omo oun ko le ba obinrin sun karakara

Lasun Alagbe

Osere fiimu Nollywood, Tonto Dikeh, ti di eni ti opo eniyan n wenu si lara bayii, leyin to so ni ita gbagba pe baale oun tele, Ogbeni Olakunle Churchill, ko ni agbara to lati ba obinrin lopo dunju.
O ni kii lo iseju kan ti o fi maa n da ti ara re sile pooropo.
Ni pato, o ni ogoji iseju aaya lo maa n lo lori obinrin.
Nipa bee, o ni arakunrin naa ni arun t awon oloyinbo n pe ni premature ejaculation.
Sugbon ko tii so oro naa tan ti awon eniyan fib ere sii hanyin mo o.
Paapaa, awon alariya egbe re ni ko ye ko maa fi gbogbo enu soro bee.
Awon kan tun so pe niwon igba to je pe oun ati Churchill ko jo wa papo mo, ko gbagbe nipa oro re, ko maa ba faaji aye re lo nibomiran.
Bakan naa, won ran Tonto Dikeh leti pe o bi omokunrin kan lanti-lanti fun okunrin yii.
Won ni ki baa se pe iseju aaya kan ni Churchill le lo lori obrin, iseju aaya naa lo di omo naa.
Lara awon ti won ti so pe ki Tonto Dike panumo ni osere fiimu ti a mo si Funke Adesiyan.
O ni ohun to ye ki Tonto Dike se ni ko gbagbe nipa ohun atijo, ko je ki afefe tuntun fe wonu aye oun.
Sugbon kii ba ni o ma ku eni kan mo ni.
Awon kan naa n ja fun Tonto Dike lori oro naa.
Lara won ni Iyabo Ojo, eni to pa owe kelenu-sonu mo Funke Adesiyan.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…