Home iroyin Nnkan buruku, e woju birikila to ta awon ibeji to bi
iroyin - Orisirisi - May 3, 2019

Nnkan buruku, e woju birikila to ta awon ibeji to bi

Olamide Yusuf

Of
Arakunrin kan, Kenneth Opoke, omo bibi ilu Ebonyi ti n se ise birikila, ni o ta awon omo re to je ibeji ni aabo milionu nairakan, iyen N5000,000, ni ipinle Rivers.
Kenneth ati iyawo re o ni owo lowo, nigba ti ti won bi awon ibeji yi.
O pe egbon ti o wa ni ipinle Rivers ti o si ni ki oun ati iyawo re wa.
Nigba ti won debe, egbon yii fun un ni amoran lati ko awon ibeji lo si ile awon omo alainiya kan, nibi ti won yoo ti san N5000,000 naa fun un.
Leyin to gba owo yii, oun ati iyawo re pada si ilu won. Nigba ti won de ilu ni owo awon agbofinro te won, ti oko si so pe odo egbon oun ni oun ko awon omo lo.
Awon agbofinro tele e de odo egbon ti o so pe oun ko awon ibeji lo, egbon so fun awon agbofinro pe iro ni aburo oun pa o, ni se lo ta awon omo re.
O ni koda ki se akoko niyi, ko sese maa ta awon omo lomo ko ti di pe o wa ta tie.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…