Home ÀKỌ̀TUN Àwọn aséwó ròyìn ìbálòpọ̀ túlàsì àwọn ọlọ́pàá
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - May 3, 2019

Àwọn aséwó ròyìn ìbálòpọ̀ túlàsì àwọn ọlọ́pàá

Yoruba bo, won ni, “ohun ti oju oku ba ri ni saree, iku lo baa waa”. Eyi lo difa fun awon to n se ise asewo ni ilu Abuja tii se oluulu Naijiria.
Won ni loooto ni awon jade lale ojo naa lati wa ounje oojo awon lo ni ile itura kan. Won ni awon ko tile tii ta rara ti awon olopaa naa fi wa ko okuta ba oro aje awon.
Won ni awon olopaa yii ko awon lati adugbo Banex lo si Utako. Won ni ko si olopaa kankan lenu ise ni oru ojo naa. Ni won ba ko awon lo seyin ile National War College. Ibe ni won ti ko ibalopo tulaasi fun awon. Won ni awon kan lo oro omi lati fi se roba idaabo bo nigba ti awon kan ko tile bikita.
Awon asewo yii ni iya ye je awon pupo nitori iru ibalopo bee ko ti inu awon wa ati wi pe ofe lo tun ba de. Won ni eyi to tun way a awon lenu ju ni iru eniyan ti won je, won ni awon lo ye ko je alaabo fun awon ti iya ba fe je sugbon ki a wo ohun ti awon naa foju awon ri.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…