Home ÀṢÀ ÀTI ÌṢE Agunbaniro ku leyin ojo meta to se igbeyawo

Agunbaniro ku leyin ojo meta to se igbeyawo

Inu ironu ni molebi awon agunbaniro kan, Ferdinand Lorwuese Kutar, si wa bayii, latari bi o se ku ojiji.
Okunrin naa to n to n sin ile baba re ni Zamfara di oloogbe leyin ojo meta to se igbeyawo niti ibile (traditional wedding) ni ipinle Benue.
Won sin Kutar ni ojo ketadinlogbon osu kerin ni ilu re, agbegbe Tse Kutar ni ipinle Benue.
Gege bi iroyin, o se igbeyawo ibile ni ojo ketala osu kerin o si di ologbe ni ojo kerindinlogun osu kan naa.
Eni ti o se oniduro fun ijoba ipinle Benue, Hon. Seta Boniface, igba keji ijoba ipinle naa, ba awon ebi oloogbe soro.
O so pe arakunrin naa je eni to mu ise lokunkundun,o wa gba ladura pe ki Olorun te so afefe ire, ti o si tun ki awon ebi re Ku araferaku.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara Orẹ Òtítọ́jù Egbìnrìn ọ̀tẹ̀ bí a ṣe ń pà…