Home ÀKỌ̀TUN Ẹ sọ́ra fún pọ̀nmọ́ onímájèlé – Jide Idris
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - April 30, 2019

Ẹ sọ́ra fún pọ̀nmọ́ onímájèlé – Jide Idris

Orisiirisii isoro lo n koju wa ni orileede yii. A ko tii bo lowo awon Boko Haram ti awon ajinigbe fi wole de, a n ja ajasegun tiwon lowo ni awon onimajele tun gbe tiwon de.
Gbogbo igbiyanju ati gbe aye ire ni o je inira fun awon eniyan kan. Awon to feran lati maa je nibi idaru. Ojo isinmi ana ni komisona fun eto ilera ni ipinle Eko kede fun awon ara ilu pe ki won sora fun ponmo fun igba die.
Komisona ni ki onikaluku wo iru ponmo ti won ba maa ra. Owo awon agbofinro te awon meta ninu awon onise ibi naa ni ijoba ibile Ojo ati Iba ni ipinle Eko. Won ni nnkan bii aago merin si mefa ni won maa ko awon ponmo onimojale naa wole ti won si bere si ni maa taa ni opo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…