Home ÀKỌ̀TUN Mínísítà ètò ààbò pè fún ìrànlọ́wọ́ Russia
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - April 24, 2019

Mínísítà ètò ààbò pè fún ìrànlọ́wọ́ Russia

Minisita fun eto aabo ni orileede yii, Ogagun Mansur Dan Ali ni “a kii wi sibe ki a ku sibe”, agbara awon ologun Naijiria ko ka Boko Haram mo.
O ni awon Nile iranlowo awon omo ogun orileede Russia. O ni idi ni pe awon orileede yii ti segun ija to le ju Boko Haram lo.
O ni ko ba dara ti ijoba apapo ba le gbo oro si oun lenu ki awon si segun awon eda buruku naa lowo Kan. Ibi ipade eleekejo ti Moscow ni minisita ti “jewo obun”.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…