Buhari balẹ̀ sí ìlú Èkó
Aare Muhammadu Buhari bale is ilu Eko gage bi gbogbo aye se n Kede lati bii ojo meta seyin.
Awon ara ilu pa ofin irinna naa mo lati bu Ola fun eni ti Ola to si. Won si n pade Aare ti erin ti eye. Gbogbo awon oba alade ati awon ijoye lo ti peju pese lati pade Aare naa.
Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara
Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara Orẹ Òtítọ́jù Egbìnrìn ọ̀tẹ̀ bí a ṣe ń pà…