Home ÀKỌ̀TUN Buhari fọwọ́ sí ẹ̀kúnwó òsìsẹ́
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - April 18, 2019

Buhari fọwọ́ sí ẹ̀kúnwó òsìsẹ́

Oni ode yii ni Aare Muhammadu Buhari fowo si ekunwo ogbon naira fun osise ti ipo re kere ju ni orileede yii. Ki eto idibo to waye ni ajo osise ti wa lenu ekunwo naa.
Awon kan tile ni Aare Buhari ko ni fowo si owo naa mo ni igba ti o ti wole ibo Aare re sugbon iyalenu nla ni o je fun awon osise ni igba ti Aare buwo lu owo naa.
Awon ajo osise kaakiri orileede yii tun wa paa lase fun gbogbo awon onile ise adani lati tele ofin yii ti won ko ba fe foju wina ofin.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Mi ò gba owó oṣù fún ọdún mẹ́jọ mi gẹ́gẹ́ bíi gómìnà Ọ̀sun

Mi ò gba owó oṣù fún ọdún mẹ́jọ mi gẹ́gẹ́ bíi gómìnà Ọ̀sun Ọrẹ Òtítọ́jù Minisita ọrọ abẹle…