Home ÀKỌ̀TUN Èmi kò nílé kankan ní òkè òkun – Dangote
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - April 15, 2019

Èmi kò nílé kankan ní òkè òkun – Dangote

Eni ti o lowo ju ni orileede yii ati ile Afirika, Alhaji Alinko Dangote ni bi awon eniyan se n pariwo pe oun lowo to, iyalenu nla lo maa je fun opo eniyan pe oun ko ni ile eyokan ni orileede miran yato fun ti Naijiria.
O ni koda oun mo pe awon osise oun ni ile kaakiri aye sugbon aaye ati owo to seku ko si fun oun lati se eyi. O ni ti oun ba ti ri ere die, bi oun se maa fi da ise miran sile ni o maa n je oun lokan.
Dangote tun ni gbogbo oun ti oun da sile bayii ni o tun ti ye ki won gba aburo paapaa julo awon nnkan to lo se araye ni anfaani. O ni eto ogbin ati imo ero komputa lo ku ti o n je oun lokan lati da sile bayii.
O ni eniyan gbodo maa yi si ibi ti araye ba n yi si ni ti olowo tabi ologbon ba fe ba egbe pe tabi ju egbe lo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…