Home ÀKỌ̀TUN Ẹ má repo pamọ́, epo kò lè wọn – NNPC
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - April 15, 2019

Ẹ má repo pamọ́, epo kò lè wọn – NNPC

Awon ajo elopo petiroolu, DPR, NNPC ati awon ajo to ku ti won jo n sise ni ki omo Naijiria ma se ra epo pamo rara, won ni ko si isoro Kankan to fi le mu ki epo naa di owon gogo.
Awon ajo yii ni awon omo Naijiria kii gbo ma se da omi eran nu rara. Won ni loooto ni ipenija kekere wa fun awon ni ile-ise, awon si ti yanju re laarin ojo kan.
Won ni eyi lo faa ti agba epo bii mewaa lojumo fi n din ku si marun-un, ni eyi ti ko ni isoro kankan fun ara ilu. Won parowa yii si awon ara ilu ki won ma tun lo bere si danu sun ile nipa rira epo pamo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara Orẹ Òtítọ́jù Egbìnrìn ọ̀tẹ̀ bí a ṣe ń pà…