Home ÀKỌ̀TUN Ọlọ́run ju ẹ̀dá lọ – Wike
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - April 4, 2019

Ọlọ́run ju ẹ̀dá lọ – Wike

Gomina ipinle Rivers Nyesom Wike ti o tun jawe olubori ninu idibo to waye ninu osu keji odun yii sugbon ti awon ajo INEC sese kede ibo re ni ana ode yii.
O ni pelu opolopo awuye-wuye ati idun –ikooko-mo. Egbe oselu PDP si tun jawe olubori. O ni ti a ko ba si fe wahala ni ipinle naa, gbogbo aye lo mo pe egbe oselu PDP lo ni ipinle naa.
Wike ba awon eniyan to padanu emi won kedun nibi idibo naa. O si dupe lowo awon omo ipinle naa ti won ko fi ajo INEC lorun sile pelu iwode wooro-wo ni gbogbo igba lati ma se je ki ajo naa gbe nnkan gbeyin won lo.
Gomina yii ni eru ko tile fi igba kankan ba oun nitori pe oun mo pe “ti won ba ju obe soke ni ìgbà igba, ibi pelebe naa lo maa fi lele. O ni eyi lo si je ki iyato to po wa ninu ibo PDP ati AA to se ipo keji. O ni ki awon araye wo ibi ti egbe PDP ti ni ibo egberin ni awon to tele awon n ni ibo ogorun-un. O ni kekere ko ni baba fi ju omo lo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…