Home ÀKỌ̀TUN Ojú ogun le fún àwọn olùgbé Èkó sí Ìbàdàn
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - April 3, 2019

Ojú ogun le fún àwọn olùgbé Èkó sí Ìbàdàn

Pinra-pinra ni ona Eko si Ibadan di lati aaro ana titi di aaro oni ni oju ona Eko si Ibadan. Ko rorun fun gbogbo awon eniyan to n lo irinajo lati Eko lo si awon ilu tabi ipinle miran, koda ko rorun fun awon to fe wo ilu Eko lati Ibadan ati agbegbe re.
Gbogbo awon olugbe adugbo bii Warewa, Magboro, Ibafo, Mowe ati agbegbe re naa lo n jara para nipa iye aago ti won wole lati ibi ise won. Awon kan de ile ni aago meji , meta ati merin ni owuro oni. Owo moto naa wa won bi oju, awon ona ti won n gbe ni ogorun naira (N100) lo di eedegbeta naira (N500).
Awon ara agbegbe naa n rawo ebe si ijoba apapo ki won jowo ba awon yara si ise ona naa. Won ni opo idaduro ona naa nii se pelu ise oju ona naa ti o n fa bii igbin.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…