Àjọ CAN s’àbẹ̀wò sí Buhari
Awon ajo elesin kirisiteeni ti awon eniyan ti n gbee kiri pe won ni awon ko ni ki Aare Muhammadu Buhari ku oriire ibo to ti jawe olubori gege bi Aare Naijiria ni eleekeji, won ni o di igba ti ejo ti Atiku Abubakar ti o je oludije du ipo Aare labe egbe oselu PDP ba pari.
Ibi abewo naa ni Aare Buhari ti n fowo soya pe oun ko ni ja awon ara orileede yii ni tanmon-on, o ni oun ko ni fi Naijiria sile jaku-jaku bi oun se baa.
Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara
Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara Orẹ Òtítọ́jù Egbìnrìn ọ̀tẹ̀ bí a ṣe ń pà…