Owo EFCC te awon Yahoo-Yahoo mefa n’Ibadan
Awon moto olowo iyebiye, ero komputa ati awon ile ni won gba lowo awon odomokunrin mefa kan ti won fura sip e won n lu jibiti lori ero alatagba.
Oga agba lori igboun safefe EFCC, Ogbeni Tonny Orilade, lo salaye oro yii fun awon oniroyin ni Abuja ni ojo isegun.
O ni lara awon nnkan ti awon gba lowo awon afurasi naa ni awon ero ibaraenisoro ati awon iwe orisirisi to je wi pe iro funfun lo kun inu awon iwe naa.
O daruko awon afurasi naa gege bii Tela Ibrahim, Awoniyi Abiodun, Oladele Wasiu, Olabiti Ajibola, Akeredolu Temidayo, ati Oyawumi Oyabode.
Oriade ni pe awon ti n gbe igbese to to lati ri daju pe awon fi imu won ko ata ofin.
O ni awon ri won mu ni agbegbe Kolapo Isola Estate ni Akobo nilu Ibadan.
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…