Ìbò gómìnà: PDP gba Adamawa mọ́ APC lọ́wọ́
Oludije gomina ninu egbe PDP, Ahmed Umar Fintiri, ti gbe akegbe re ni APC, Jibrila Bindow, sanle o.
Oru oni ni won pari afikun idibo, eyi ti awon oloyinbo n pe ni supplementary election, ni ipinle naa.
Fintiri ni ibo 376, 552 nigba ti Bindow ni 336,336.
Itumo eyi ni pe oludije aare fun PDP, Atiku Abubakar, ti gba ipinle re fun egbe naa, tori omo Adamawa ni.
Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja
Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…