Fayemi tun wọlé ìbò gómìnà padà l’Ékìtì
Gomina ti won dibo yan ni ipinle Ekiti, Kayode Fayemi ti egbe oselu APC ni Ogbeni Kolapo Olusola to je oludije du ipo gomina fun egbe oselu PDP ni ipinle naa gbe lo si ile ejo. O ni oun ni oun wole ibo ti awon di ninu osu kerin odun yii.
Adajo ile ejo giga naa to fi ikale si ilu Abuja, Adajo Stephen Adah gbo ejo awon agbejoro ti otun ati ti osi. O ni Kayode Fayemi ti awon ajo INEC kede naa ni o wole ibo naa.
Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari
Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…