Home ÀKỌ̀TUN Melaye nìkan ló padà nínú àwọn ọlọ̀tẹ̀ 16 tó bínú lọ – Oshiomole
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - March 26, 2019

Melaye nìkan ló padà nínú àwọn ọlọ̀tẹ̀ 16 tó bínú lọ – Oshiomole

Aare patapata fun egbe oselu APC, Adams Oshiomole ni o n ba awon oniroyin soro laipe yii, nigba ti won luu lenu gboro nipa Aare ile igbimo asofin agba. O ni ko si ewu ninu oro naa. O ni ti asiko ba ti to, o maa yanju ara re nitori pe ile igbimo asofin agba naa ti di irorun fun egbe oselu APC.
O ni gbogbo awon olote to n degbe ru lo ti binu lo. O ni Olorun ko fi igba kan wa leyin olote, o ni ninu awon seneto merindinlogun to binu lo ati Aare ile igbimo naa, o ni Dino Melaye nikan ni kadara da pada. Lara awon Senato APC to binu lo si egbe oselu PDP nigba naa ni – Bukola Saraki, Dino Melaye, Rabiu kwankwaso, Lanre Tejuoso, Abdulazeez Nyako, Monsurat Sunmonu ati bee bee lo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…