Home ÀKỌ̀TUN Ọ̀mìn ni ẹgbẹ́ òsèlú APC àti PDP ta nínú èsì ìbò gómìnà
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - March 25, 2019

Ọ̀mìn ni ẹgbẹ́ òsèlú APC àti PDP ta nínú èsì ìbò gómìnà

Ninu ipinle mefa ti esi ibo won ko kese jari ni ojo kesan-an osu keta odun yii, ni eyi to mu ki ajo eleto idibo INEC sun awon idibo naa si ojo ketalelogun osu yii.
Ipinle merin ni esi ibo won ti jade ti egbe oselu APC jawe olubori ni ipinle Plateau ati Kano. Simon Lalong ati Abdullahi Ganduje ni awon gomina naa. Aminu Tambuwal ati Samuel Ortom ni awon gomina to wole ni ipinle Sokoto ati Benue, ti won si je egbe oselu PDP.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…