Home ÀKỌ̀TUN Saraki ló pàdánù jù nínú ìdìbò 2019 – BMO
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - March 22, 2019

Saraki ló pàdánù jù nínú ìdìbò 2019 – BMO

Orisiirisii itupale lo n lo lowo lori idibo Aare inu osu keji to koja. Onikaluku si n gbee jade gege bi oju ti won fi wo eto idibo naa. Eyi naa lo fa abajade awon ajo oniroyin Aare Muhammadu Buhari ti won pe oruko ara won ni Buhari Media Organisation (BMO).
Gege bi olori ajo naa, Niyi Akinsiju ati akowe agba Cassidy Madueke se salaaye pe nigba ti awon yannana eto idibo naa yebe-yebe, aanu Oloye Bukola Saraki ni o se awon ju nitori pe pelu ipo re gege bii eni keta ni orileede yii, ti o wa padanu ibo ni adugbo re. Won ni eyi ko tii waye ri ninu itan lati igba ti eto idibo awa-ara-wa ti bere.
Won ni lona miran ti awon tun fi oju woo ni pe eegun re ko tun le se mo ninu agbo oselu orileede yii mo, ni eyi to buru jojo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…