Nnkan nla! Ile ejo le Oyetola danu, won ni Ademola Adeleke lo wole!
Ile ejo to n gbo ejo ibo laarin Senito Ademola Adeleke ati Gomina Ipinle Osun, Adegboyega Oyetola, ti so pe Adeleke lo wole gomina o.
Odun to lo ni won dibo naa, ti egbe PDP ati APC sit a kan-angbon.
Nigba ti won koko di i, ajo INEC ni eni kankan ko wole, ti won si tun ibo di ni awon ibi kan, paapaa ni adugbo Ife.
Sugbon leyin opo atotonu, ile ejo naa ni Adeleke lo wole, kii se Oyetola rara.
Mi ò gba owó oṣù fún ọdún mẹ́jọ mi gẹ́gẹ́ bíi gómìnà Ọ̀sun
Mi ò gba owó oṣù fún ọdún mẹ́jọ mi gẹ́gẹ́ bíi gómìnà Ọ̀sun Ọrẹ Òtítọ́jù Minisita ọrọ abẹle…