Home ÀKỌ̀TUN INEC lu jìbìtì ìpínlẹ̀ mẹ́rin fún Buhari – Atiku
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - March 22, 2019

INEC lu jìbìtì ìpínlẹ̀ mẹ́rin fún Buhari – Atiku

Igbakeji Aare tele ri ni orileede yii to tun je oludije du ipo Aare labe egbe oselu PDP, Alhaji Atiku Abubakar ni o n salaye fun awon oniroyin idi ti ko fi gba pe Aare Buhari jawe olubori gege bi awon eleto idibo ile wa (INEC) se kede fun araye leyin idibo Aare to koja lo.
O ni iro nla lo wa nidii re pe Aare Buhari jawe olubori ni ipinle mokandinlogun nigba ti won ni oun jawe olubori ni ipinle mejidinlogun ti oluulu wa Abuja wa ninu re.
Alhaji Atiku ni oun ni o jawe olubori ni awon ipinle Kogi, Kaduna, Gombe ati Niger. O ni eri to daju si wa lara ohun ti oun n ko lo si ile ejo bayii. O ni ole ojukoroju eleyii ti oun ko si fe iru ireje bee.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…