Home ÀKỌ̀TUN Kò sí ẹni tó lè yọ mí lẹ́gbẹ́ PDP – Agbaje
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - March 21, 2019

Kò sí ẹni tó lè yọ mí lẹ́gbẹ́ PDP – Agbaje

Oludije du ipo gomina ni ipinle Eko, Alagba Jimi Agbaje ni o ni awon kan n gbe iroyin eleje kiri pe oun ti fi egbe oselu PDP sile nitori pe awon kan n dun ikooko mo oun ninu egbe naa.
O ni ko si eni to le yo oun legbe, nitori wi pe ikooko didun Kankan ko se eru ba oun. O ni loooto ni awon kan ninu egbe ni oun ko lo owo ti egbe gbe sile daadaa ni eyi to faa ti egbe oselu naa se fidi remi.
Agbaje ni owo oun funfun lai ni idoti kankan. O ni awon alase egbe naa lo seto nina owo sugbon ti kadara ko se awon lore.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…