Home ÀKỌ̀TUN NDLEA fọwọ́ sìnkún òfin mú ọmọ Ghana pẹ̀lú oògùn olóró nínú tòmátì
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - March 17, 2019

NDLEA fọwọ́ sìnkún òfin mú ọmọ Ghana pẹ̀lú oògùn olóró nínú tòmátì

Papako ofurufu ti muritala Muhammed to wa ni ilu Ikeja ti ipinle Eko ni owo sinkun ofin awon ajo NDLEA ti te arakunrin Gyan Paul to je omo orileede Ghana.
Inu agolo tomato ni o dogbon ko awon oogun oloro ti ijoba Naijiria fofin de naa si. O wa gbe gbogbo re si inu apo ti gbogbo eniyan mo si “Ghana must go”.
Orileede Indonesia ni won ni awon oogun oloro naa n lo. Oogun oloro ti o le ni iwon kilomita meji. Adajo sun idajo naa sun ojo ketala, osu karun-un odun yii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…