Home ÀKỌ̀TUN Ìjàm̀bá iná Eko sọ ẹ̀jẹ̀ di wíwọ́n
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - March 14, 2019

Ìjàm̀bá iná Eko sọ ẹ̀jẹ̀ di wíwọ́n

Ijamba ina to sele ni ana ni ita-faji to wa ni ipinle Eko ti opo akekoo ha si inu ijamba naa, ti awon emi kan sofo ma tun ti ba ona miran yo.
Awon kan ti ori ko yo ninu ijamba naa nilo eje gege bi akowe agba ajo Red Cross se pariwo re sita. Ipolongo yi si n ran kaakiri ni ori ero ayelujara.
Won ni eni ti Olorun ba bun ki o bun awon, opo wa ni ko kuku mo pe apoju eje maa n pa eniyan. Eni ti o ba setan, won ni ki o lo si aja karun-un, ile-iwosan Island (5th floor Island marternity, Lagos).

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…