Osere fiimu ni ki awon okunrin to laya nile sinmi lile obinrin miran kiri
Yusuf Asewale
Osere-binrin Angel Ufuoma ti pariwo sita pe ki awon okunrin ti won ti ni iyawo nile fi oun lorun sile ki won je ki oun simi.
Ninu atejade kan to fi sori ero alatagba Instergram laipe yii lo ti ke gbajare naa.
Ufuoma ro won pe ki won gbaju mo iyawo won.
O fi kun un pe gbogbo nnkan ti won ba ni ki won maa fun iyawo ile won, ki won si je olotito si iyawo won.ki won ye wa ohun ti won ko sonu kiri.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…