Home ÀKỌ̀TUN Jimi Agbaje kí Babajide Sanwo olu kú oríire
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - March 10, 2019

Jimi Agbaje kí Babajide Sanwo olu kú oríire

Oludije du ipo gomina ni ipinle Eko, Ogbeni Jimi Agbaje ki Babajide Sanwo-Olu ku oriire bo se jawe olubori nibi idibo to waye ni ana ojo Abameta, ojo kejo osu keta odun yii.
Jimi ni ti a ba n ja bi ki a ku ko, o ni ti eniyan meji ba si n ta ayo, ti ko ba je omi, enikan ni lati yege. O ni eyi lo mu ki oun ki Sanwo-olu ku oriire.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…