Home ÀKỌ̀TUN APC wọlé ní Ogun àmọ́ APM ní àwọn kò gbà
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - March 10, 2019

APC wọlé ní Ogun àmọ́ APM ní àwọn kò gbà

Ipinle Ogun wa lara awon ipinle ti awon opo eniyan n reti eni to maa jawe olubori ni ibe. Idibo ibe naa waye bii ti gbogbo ipinle to ku se waye.
Ohun to fa eyi ko ju ti gomina ipinle Ogun Oloye Ibikunle Amosu to gbe oludije gomina miran kale ni igba ti o wole ipo Seneto ni oruko egbe oselu APC.
Sise oju meji yii naa lo faa ti egbe fi le kuro fun igba die. Ajo INEC ipinle naa wa kede Dapo Abiodun ti egbe oselu APC pe oun lo jawe olubori nibi ibo gomina naa sugbon egbe oselu APM ni ojoro wa ninu idibo naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara Orẹ Òtítọ́jù Egbìnrìn ọ̀tẹ̀ bí a ṣe ń pà…