Home ÀKỌ̀TUN Wọ́n tún ti já àpótí ìbò gbà ní Rivers
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - March 9, 2019

Wọ́n tún ti já àpótí ìbò gbà ní Rivers

Iroyin yajo-yajo to te wa lowo je ki a mop e pelu gbogbo eto ati ipalemo ohun idunkoko mo lori pe enikeni to ba ji apoti ibo gbe yoo kan idin ninu iyo. Awon ikede yii ko tu irun Kankan lara awon alagidi talaka. Awon ti emi won gan-an ko jo won loju.
Eto ibo bere daadaa ni ipinle Rivers nitori pe gogbo awon osise idibo naa ni won ti tete de aaye won ni asiko. Sugbon bi eto ti bere naa ni awon to di iha mora kan dede de, ti won si ko ibon dani. Ko si eni to le ko won loju paapaa ni agbegbe Abonnema ni woodu 5,6,7,10,11 ati 12.
Egbe ti awon eni ibi yii n ja fun ko tii han si araye.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…