Home ÀKỌ̀TUN Ìwádìí lórí àwọn Sójà tó wọ ilé Kọmísọ́nà – Army
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - March 8, 2019

Ìwádìí lórí àwọn Sójà tó wọ ilé Kọmísọ́nà – Army

Ile-ise awon ologun ile wa ni iwadii to gbopan ti n lo lowo bayii lori awon soja to wo ile komisona fun eto-eko ni ipinle Rivers lasiko idibo, komisona naa,Dr. Tamunosisi Gogo-jaja daa bii ogbon nigba ti ara fun-un nipa fifi kamera to n ya aworan (CCTV) si inu ile naa, gbogbo won si go si ibikan titi ti won fi lo nigba ti won ko ri enikankan.
Gbogbo aye si n wo won bi won se gba yara idana wole. Fonran fidio yii ti gba gbogbo ori ero ayelujara. Fidio naa n ran kiri bi ina inu oye ni.
Nigba ti iroyin naa da ago awon ologun, won ni awon naa ti rii, iwadii si n lo lori re nitori pe, ko leto fun ologun kankan lati se egbe leyin egbe oselu kankan.
Gege bi Col. Sagir Musa se gbenu so fun Ogagun Tukur Buratai to je olori won naa. O ni awon maa je ki araye mo abo iwadii awon.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Mi ò gba owó oṣù fún ọdún mẹ́jọ mi gẹ́gẹ́ bíi gómìnà Ọ̀sun

Mi ò gba owó oṣù fún ọdún mẹ́jọ mi gẹ́gẹ́ bíi gómìnà Ọ̀sun Ọrẹ Òtítọ́jù Minisita ọrọ abẹle…