Home Orisirisi Ọ̀ọ̀ni sọ fún Buhari pé kó se ẹ̀tọ́ fún gbogbo ọmọ Nàìjíríà
Orisirisi - Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - March 7, 2019

Ọ̀ọ̀ni sọ fún Buhari pé kó se ẹ̀tọ́ fún gbogbo ọmọ Nàìjíríà


Ooni ti Ife, Oba Adeyeye Ogunwusi, ti gba Aare Muhammadu Buhari nimoran pe ki o se eto fun gbogbo omo ati eya orile-ede yii ninu ijoba re to n bo.
O ni ko se ise baba lori gbogbo won.
Ooni ni bi Buhari se wole eekeji yii, ko gbodo gbe eya kan ga ju ekeji lo lokan re, tori gbogbo wa naa nia jo ni Naijiria.
Kabiyesi se alaye oro yii nigba ti awon lobaloba se abewo si Aare Buhari ni ile ijoba Aso Rock ni Abuja.
Aare naa wa fi da awon loju pe didun ni osan yoo so laye isejoba to kan yii, eyi ti won n pe ni ‘Next Level’.
Aare Buhari ke si awon oba alaye naa pe ki won jowo maa fwo sowopo pelu awon agbofinro lati maa foju odaran han, tori awon ni won mo gbogbo koro ti awon kranbaani naa le fe maa sa si.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…