Home ÀKỌ̀TUN Ilé ẹjọ́ gba Atiku láàyè láti ka ìbò Buhari
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - March 7, 2019

Ilé ẹjọ́ gba Atiku láàyè láti ka ìbò Buhari

Ile-ejo giga tiribuna to fi ikale si ilu Abuja ti gba oludije du ipo Aare labe egbe oselu PDP, Alhaji Atiku Abubakar laaye lati lo ma aka awon ibo to le ni milionu meedogun kaakiri orileede yii ti ajo INEC ni o gbe Aare Muhammadu Buhari wole eleekeji.
Atiku Abubakar ati awon egbe oselu PDP ni awon ko fara mo esi ibo naa nitori pe ojoro ti po ju ninu re. Won ni bi awon si se woye ibo naa, Atiku ni o jawe olubori.
Eyi lo mu won gba ile-ejo lo pelu gbogbo arowa ti awon elegbejegbe ati ologbajogba pa si won nipa ero naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Mi ò gba owó oṣù fún ọdún mẹ́jọ mi gẹ́gẹ́ bíi gómìnà Ọ̀sun

Mi ò gba owó oṣù fún ọdún mẹ́jọ mi gẹ́gẹ́ bíi gómìnà Ọ̀sun Ọrẹ Òtítọ́jù Minisita ọrọ abẹle…