Home ÀKỌ̀TUN Ìbò ni kí ẹ dì, ẹ má ṣe jà – Asiwaju Tinubu
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - March 7, 2019

Ìbò ni kí ẹ dì, ẹ má ṣe jà – Asiwaju Tinubu

Asiwaju patapata fun egbe oselu APC, Bola Ahmed Tinubu ni o n parawo fun awon ara Eko ni ojo’ru tii se asekagba ipolongo ibo fun ipo gomina ati awon to n lo si ile-igbimo asofin ipinle.
O ni ki awon ara ilu tuyaaya ki won sit un tu yaaya jade lati wa dibo fun egbe olosusu owo. Ki awon le jo pawopo gbe ipinle Eko de ebute ogo. O ni ii ise ogun odun ti awon jijo bere maa baa baje.
Tinubu ni eniyan to sun mo milionu mefa lo ti leto lati dibo ni ipinle Eko ti won si ti gba kaadi alalope sowo. O ni ko dara to ki o je wi pe milionu kan pere lo jade lati dibo naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…