Home ÀKỌ̀TUN Ẹgbẹ́ òsèlú APC kò rán ẹlẹ́bẹ̀ sí PDP nítorí ilé-ẹjọ́ – Keyamu
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - March 6, 2019

Ẹgbẹ́ òsèlú APC kò rán ẹlẹ́bẹ̀ sí PDP nítorí ilé-ẹjọ́ – Keyamu

Agbejoro agba to n sise pelu egbe oselu APC, Festus Keyamo ni arogun-ma-sa ni egbe oselu APC. O ni ko si igba kankan ti egbe awon lo ran elebe si egbe oselu PDP nitori ile-ejo ti wọn ni awon fẹ lọ.
O ni awon kan ni awon ti ranse si ilu Oba ati awon orileede miran lati wa parowa si egbe oselu PDP ki won ma se lọ si ile-ẹjọ mo. O ni ko si ohun ti o joo nitori pe awon ko lebo leru.
O ni gege bi agbejo agba ti oun naa je, ile-ejo o ki n dede so eniyan tabi egbe sewon. O ni iko mejeeji lo maa ro ejo pelu eri ti o daju, ki idajo to waye.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…