Èmi ò dupò olóri ilé ìgbìmọ̀ asòfin báyìí – Dogara
Olori ile igbimo asofin, Yakubu Dogara ni iro ni awon eniyan ati iroyin n gbe kiri pe oun ti bere si ni rin irn bi oun se maa di olori ile igbimo asofin eleekesan-an to maa bere ninu osu kefa.
O ni bayii, o si ku osu meta gbako fun awon lati lo, ni eyi to se pataki fun ojo iwaju orileede yii. O ni awon ko gbodo fi ete sile ki awon maa pa lapa-lapa. O ni ti asiko ba to lati mo eni to maa di olori, gbogbo oju ni yoo ri.
Ogbeni Turaki Hassan to je olubani-damoran pataki fun Dogara lo salaye yii fun awon oniroyin.
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…