Home iroyin Ìdí tí mo fi padà sí APC – Akala
iroyin - Orisirisi - Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - March 2, 2019

Ìdí tí mo fi padà sí APC – Akala


Gomina Ipinle Oyo tele, Otunba Alao Akala, ti so pe bi oun se wo sakun ibi ti nnkan n lo ninu ibo gomina to n bo lo je ki oun paa sinu egbe APC.
Gomina naa ti binu kuro ninu egbe naa tele, to si ni oun naa fe di gomina leeekan sii ninu egbe oselu miran.
Sugbon oro yi biri ni ijeta si ana.
O ni oun ti woye pe ofuutu-feete ni igbese ti oun n gbe tele, to si je pe pipada si APC ni oun to fogbon yo.
Bakan naa, Akala ni awon omoleyin oun fe ki oun pada si APC, to si je pe orin ti won bad a ni oun n gbe, ilu ti won bal u ni oun n jo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…