Home Entertainment Business Àwọn aláìmọ̀kan ló ń bú mi lórí ọ̀rọ̀ Bàbá Sùwé – Dele Odule

Àwọn aláìmọ̀kan ló ń bú mi lórí ọ̀rọ̀ Bàbá Sùwé – Dele Odule

Osere fiimu pataki, Dele Odule, ti bu enu ate lu awon to n yo suti ete si i lori oun ti egbe awon osere TAMPAN se fun gbajugbaja alawada, Baba Suwe, ti ara re ko ya.
Nigba ti Odule si je alaga egbe naa, o ni awon seranwo se b’oo ti mo, elewa Sapon, nipa fifun Baba Suwe ni egberun lona ogorun naira – N100,000.
Eyi fa ki awon eniyan kan maa bu u, tori won ro pe owo naa kere.
Sugbon nigba ti Odule n fesi le oro naa ninu iforowanilenuwo kan ninu iwe iroyin ‘The Nation’, , o ni aimokan ati ai larojinle lo le fa ki won bu enu ate lu oun tabi egbe naa.
O ni TAMPAN sapa tie, ati pe ti oro ba sele bo se se si Baba Suwe, oniruuru eniyan ati egbe lo ye ko dide iranwo, kii se egbe osise tabi osere nikan.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ WASCCE tó fi ìsekúse parí ìdánwò

Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ WASCCE tó fi ìsekúse parí ìdánwò Yìnká Àlàbí O ma se o! Awo̩n ake̩ko̩o̩…