Home ÀKỌ̀TUN Abdulsalam ṣe ìpàdé bòńkẹ́lẹ́ pẹ̀lú àwọn APC àti PDP
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - March 2, 2019

Abdulsalam ṣe ìpàdé bòńkẹ́lẹ́ pẹ̀lú àwọn APC àti PDP

Aare tele ri ni orileede yi, Ajagunfehinti Abdulsalam Abubakar to je oludari ajo “petu si aawo” (National Peace Committee NPC), se ipade bonkele pelu Aare Orileede yii to tun jawe olubori nibi eto idibo to waye laipe, Mohammadu Buhari ni ile ijoba to wa ni Aso Rock ni Abuja.
Abudulsalam Abubakar, Ojise Olorun Matthew Kuka, Alagba Cardinal John Onaiyekan ati Alagba Atta Barkindo tun se ipade bonkele miran pelu Alhaji Atiku Abubakar, Peter Obi, Omooba Uche Secondus ati Oloye Bukola Saraki nipa abajade ibo ti a sese pari.
Won ko salaye abo ipade yii fun oniroyin kankan, sugbon “gbogbo wa ni isowo ogun, ti eja ba so lodo, a mo iye to to”. Ko ye ki a ya “amoran bini Oyo, to ri kete omi lori to tun n beere ibo lo da”. Leyn idibo Aare, Alhaji Atiku Abubakar yari pe oun ati awon egbe oselu PDP ko ni gba esi idibo naa wole nitori pe o ni makaruru ninu lopo. Koda, won ni ile ejo lo maa pari re fun awon.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara Orẹ Òtítọ́jù Egbìnrìn ọ̀tẹ̀ bí a ṣe ń pà…