Atiku gba ìlú Abuja, Buhari mú Kwara
Ibo 152,224 ni Mohammadu Buhari ri nigba ti Atiku Abubakar ri 259, 997. Eyi si mu ki Atiku bori ni olu ilu naa.
Buhari gba ipinle Kwara mo Atiku lowo pelu ibo 308,984 nigba ti Atiku ni 138,184.
Esi ibo si n te siwaju.
Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja
Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…