Ogun eniyan ti padanu emi won ninu rogbodiyan oselu
Ogun eniyan ti padanu emi won ninu rogbodiyan oselu
Ominu ti n ko opolop eniyan o, tori itajesile n gbile sii lasiko ibo yii.
Bayii, won ni o ti to ogun eniyan tie mi won ti ba ibo naa lo.
Lara awon ipinle ti gudugbe ti ja ni Rivers, Bayelsa, Eko ati Oyo.
Koda, won ni soja kan wa lara awonti won pa ni Rivers.
Ni Eko, okunrin kan ti won pe ni baba ati omo egbe OPC kan gbemi mi lojo Satide.
Bakan naa lo se sele ni Ibadan, nigba ti a won yinbon pa omokunrin an ti won pe oruko re ni Monsuru.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…