Ni Kwara, ori O TO GEE di O TO’PE
Awon omo egbe APC n dunnu sinkin bayii ni o, pelu ireti pe nnkan n senu rere fun won ninu esi ibo kaakiri awon ipinle naa.
APC n ba PDP wo ijakadi, paapaa won fe gba ijoba ipine naa ti won gba pe o wa lowo Dokita Bukola Saraki.
Idi niyi ti asa ipolongo ibo wn fi je O TO GEE, eyi ti awon Yoruba maa n pari pe alubata kii darin.
Minisita fun Oro Iroyin ati Aasa, Alhaji Lai Mohammed, lo n se agbateru ipeninija fun Saraki naa.
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…