Nnkan kan naa ni APC ati PDP – Wizkid
Akorin pataki kan, Ayo Balogun, ti a mo si Wizkid, ti so pe okan ko gbekan ni oro egbe oselu mejeeji to wa niwaju, iyen APC ati PDP.
O ni iru kan-un tii tu igba oti ni won.
Wizkid so lori ero alatagba pea won omo Naijiria ni lati taji, ki won gba ara won kuro lowo awon amunising.
Igba to n fi ibinu re han lori bi won se sun idibo siwaju lo so eleyii.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…